Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 64:11-12 Yorùbá Bibeli (YCE)

11. Ile wa mimọ́ ati ologo, nibiti awọn baba wa ti nyìn ọ, li a fi iná kun: gbogbo ohun ãyo wa si ti run.

12. Iwọ o ha da ara rẹ duro nitori nkan wọnyi, Oluwa? iwọ o ha dakẹ, ki o si pọn wa loju kọja àla?

Ka pipe ipin Isa 64