Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 63:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi nikan ti tẹ̀ ohun-elò ifunti waini; ati ninu awọn enia, ẹnikan kò pẹlu mi: nitori emi tẹ̀ wọn ninu ibinu mi, mo si tẹ̀ wọn mọlẹ ninu irunú mi; ẹ̀jẹ wọn si ta si aṣọ mi, mo si ṣe gbogbo ẹ̀wu mi ni abawọ́n.

Ka pipe ipin Isa 63

Wo Isa 63:3 ni o tọ