Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 63:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Laiṣiyemeji iwọ ni baba wa, bi Abrahamu tilẹ ṣe alaimọ̀ wa, ti Israeli kò si jẹwọ wa: iwọ Oluwa, ni baba wa, Olurapada wa; lati aiyeraiye ni orukọ rẹ.

Ka pipe ipin Isa 63

Wo Isa 63:16 ni o tọ