Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 62:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gẹgẹ bi ọdọmọkunrin ti igbé wundia ni iyawo, bẹ̃ni awọn ọmọ rẹ ọkunrin yio gbe ọ ni iyawo: ati bi ọkọ iyawo ti iyọ̀ si iyawo, bẹ̃ni Ọlọrun rẹ yio yọ̀ si ọ.

Ka pipe ipin Isa 62

Wo Isa 62:5 ni o tọ