Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 61:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori emi Oluwa fẹ idajọ, mo korira ijale ninu aiṣododo; emi o si fi iṣẹ wọn fun wọn ni otitọ, emi o si ba wọn da majẹmu aiyeraiye.

Ka pipe ipin Isa 61

Wo Isa 61:8 ni o tọ