Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 61:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o yọ̀ gidigidi ninu Oluwa, ọkàn mi yio yọ̀ ninu Ọlọrun mi; nitori o ti fi agbáda wọ̀ mi, o ti fi aṣọ ododo bò mi, gẹgẹ bi ọkọ iyawó ti iṣe ara rẹ̀ lọṣọ́, ati bi iyawó ti ifi ohun ọṣọ́ ṣe ara rẹ̀ lọṣọ́.

Ka pipe ipin Isa 61

Wo Isa 61:10 ni o tọ