Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 60:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nipo idẹ emi o mu wura wá, nipo irin emi o mu fadaka wá, ati nipo igi, idẹ, ati nipo okuta, irin: emi o ṣe awọn ijoye rẹ ni alafia, ati awọn akoniṣiṣẹ́ rẹ ni ododo.

Ka pipe ipin Isa 60

Wo Isa 60:17 ni o tọ