Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 60:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni bi a ti kọ̀ ọ silẹ, ti a si ti korira rẹ, tobẹ̃ ti ẹnikan kò kọja lãrin rẹ, emi o sọ ọ di ogo aiyeraiye, ayọ̀ iran-de-iran ọ̀pọlọpọ.

Ka pipe ipin Isa 60

Wo Isa 60:15 ni o tọ