Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 58:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ãwẹ̀ iru eyi ni mo yàn bi? ọjọ ti enia njẹ ọkàn rẹ̀ ni ìya? lati tẹ ori rẹ̀ ba bi koriko odo? ati lati tẹ́ aṣọ ọ̀fọ ati ẽru labẹ rẹ̀? iwọ o ha pe eyi ni ãwẹ̀, ati ọjọ itẹwọgba fun Oluwa?

Ka pipe ipin Isa 58

Wo Isa 58:5 ni o tọ