Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 58:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nwọn nwá mi lojojumọ, nwọn si ni inu didun lati mọ̀ ọ̀na mi, bi orilẹ-ède ti nṣe ododo, ti kò si fi ilàna Ọlọrun wọn silẹ: nwọn mbere ilàna ododo wọnnì lọwọ mi; nwọn a ma ṣe inu didun ati sunmọ Ọlọrun.

Ka pipe ipin Isa 58

Wo Isa 58:2 ni o tọ