Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 58:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni inu rẹ yio dùn si Oluwa, emi o si mu ọ gùn ibi giga aiye, emi o si fi ilẹ níni Jakobu baba rẹ bọ́ ọ: nitori ẹnu Oluwa li o ti sọ ọ.

Ka pipe ipin Isa 58

Wo Isa 58:14 ni o tọ