Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 57:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lẹhin ilẹkùn ati opó ilẹkun ni iwọ si ti gbe iranti rẹ soke: nitori iwọ ti fi ara rẹ hàn fun ẹlomiran dipò mi, iwọ si ti goke: iwọ ti sọ akete rẹ di nla, iwọ si ba wọn dá majẹmu; iwọ ti fẹ akete wọn nibiti iwọ ri i.

Ka pipe ipin Isa 57

Wo Isa 57:8 ni o tọ