Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 57:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati iwọ ba kigbe, jẹ ki awọn ẹgbẹ rẹ ki o gbà ọ; ṣugbọn ẹfũfu ni yio gbá gbogbo wọn lọ; emi yio mu wọn kuro: ṣugbọn ẹniti o ba gbẹkẹ rẹ̀ le mi yio ni ilẹ na, yio si jogun oke mimọ́ mi.

Ka pipe ipin Isa 57

Wo Isa 57:13 ni o tọ