Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 57:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. OLODODO ṣegbe, kò si ẹniti o kà a si: a mu awọn alãnu kuro, kò si ẹniti nrò pe a mu olododo kuro ṣaju ibi.

2. On wọ̀ inu alafia: nwọn simi lori akete wọn, olukuluku ẹniti nrin ninu iduroṣinṣin rẹ̀.

Ka pipe ipin Isa 57