Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 55:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jẹ ki enia buburu kọ̀ ọ̀na rẹ̀ silẹ, ki ẹ̀lẹṣẹ si kọ̀ ironu rẹ̀ silẹ: si jẹ ki o yipada si Oluwa, on o si ṣãnu fun u, ati si Ọlọrun wa, yio si fi jì li ọpọlọpọ.

Ka pipe ipin Isa 55

Wo Isa 55:7 ni o tọ