Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 55:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiyesi i, iwọ o pe orilẹ-ède ti iwọ kò mọ̀, ati orilẹ-ède ti kò mọ̀ ọ yio sare wá sọdọ rẹ, nitori Oluwa Ọlọrun rẹ, ati nitori Ẹni-Mimọ Israeli; nitori on ti ṣe ọ li ogo.

Ka pipe ipin Isa 55

Wo Isa 55:5 ni o tọ