Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 51:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori Oluwa yio tù Sioni ninu; yio tú gbogbo ibi ofo rẹ̀ ninu; yio si ṣe aginju rẹ̀ bi Edeni, ati aṣálẹ rẹ̀ bi ọgbà Oluwa, ayọ̀ ati inudidùn li a o ri ninu rẹ̀, idupẹ, ati ohùn orin.

Ka pipe ipin Isa 51

Wo Isa 51:3 ni o tọ