Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 5:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Egbe ni fun awọn ti ima dide ni kùtukutu, ki nwọn le ma lepa ọti lile; ti nwọn wà ninu rẹ̀ titi di alẹ, titi ọti-waini mu ara wọn gbona!

Ka pipe ipin Isa 5

Wo Isa 5:11 ni o tọ