Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 49:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wipe, O ṣe ohun kekere ki iwọ ṣe iranṣẹ mi, lati gbe awọn ẹyà Jakobu dide, ati lati mu awọn ipamọ Israeli pada: emi o si fi ọ ṣe imọlẹ awọn Keferi, ki iwọ ki o le ṣe igbala mi titi de opin aiye.

Ka pipe ipin Isa 49

Wo Isa 49:6 ni o tọ