Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 49:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bayi ni Oluwa wi, a o tilẹ̀ gbà awọn ondè kuro lọwọ awọn alagbara, a o si gbà ikogun lọwọ awọn ẹni-ẹ̀ru; nitori ẹniti o mba ọ jà li emi o ba jà, emi o si gbà awọn ọmọ rẹ là.

Ka pipe ipin Isa 49

Wo Isa 49:25 ni o tọ