Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 49:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi ni Oluwa Jehofa wi, Kiyesi i, emi o gbe ọwọ́ mi soke si awọn Keferi, emi o si gbe ọpágun mi soke si awọn enia, nwọn o si gbe awọn ọmọkunrin rẹ wá li apa wọn, a o si gbe awọn ọmọbinrin rẹ li ejìka wọn.

Ka pipe ipin Isa 49

Wo Isa 49:22 ni o tọ