Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 49:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbe oju rẹ soke yika kiri, si kiyesi i: gbogbo awọn wọnyi ṣà ara wọn jọ, nwọn si wá sọdọ rẹ. Oluwa wipe, Bi mo ti wà, iwọ o fi gbogbo wọn bò ara rẹ, bi ohun ọṣọ́, nitõtọ, iwọ o si há wọn mọ ara, bi iyawo.

Ka pipe ipin Isa 49

Wo Isa 49:18 ni o tọ