Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 47:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina gbọ́ eyi, iwọ alafẹ́, ti o joko li ainani, ti o wi li ọkàn rẹ pe, Emi ni, kò si si ẹlomiran lẹhin mi: emi ki yio joko bi opo, bẹ̃ni emi ki yio mọ̀ òfo ọmọ.

Ka pipe ipin Isa 47

Wo Isa 47:8 ni o tọ