Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 47:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Arẹ̀ mu ọ nipa ọpọlọpọ ìgbimọ rẹ. Jẹ ki awọn awoye-ọrun, awọn awoye-irawọ, awọn afi-oṣupasọ-asọtẹlẹ, dide duro nisisiyi, ki nwọn si gbà ọ lọwọ nkan wọnyi ti yio ba ọ.

Ka pipe ipin Isa 47

Wo Isa 47:13 ni o tọ