Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 45:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kán silẹ, ẹnyin ọrun, lati oke wá, ki ẹ si jẹ ki ofurufu rọ̀ ododo silẹ; jẹ ki ilẹ ki o là, ki o si mu igbala jade; si jẹ ki ododo ki o hù soke pẹlu rẹ̀; Emi Oluwa li o dá a.

Ka pipe ipin Isa 45

Wo Isa 45:8 ni o tọ