Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 45:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bayi li Oluwa wi, ẹniti o dá awọn ọrun; Ọlọrun tikararẹ̀ ti o mọ aiye, ti o si ṣe e; o ti fi idi rẹ̀ mulẹ, kò da a lasan, o mọ ọ ki a le gbe inu rẹ̀: Emi ni Oluwa; ko si ẹlomiran.

Ka pipe ipin Isa 45

Wo Isa 45:18 ni o tọ