Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 45:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

BAYI ni Oluwa wi fun ẹni-ororo rẹ̀, fun Kirusi, ẹniti mo di ọwọ́ ọtún rẹ̀ mu, lati ṣẹ́gun awọn orilẹ-ède niwaju rẹ̀; emi o si tú amure ẹgbẹ awọn ọba, lati ṣi ilẹkùn mejeji niwaju rẹ̀, a ki yio si tì ẹnu-bode na;

Ka pipe ipin Isa 45

Wo Isa 45:1 ni o tọ