Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 44:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹniti o sọ àmi awọn eke di asan, ti o si bà awọn alafọṣẹ li ori jẹ, ti o dá awọn ọlọgbọn pada, ti o si sọ imọ̀ wọn di wère.

Ka pipe ipin Isa 44

Wo Isa 44:25 ni o tọ