Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 44:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iyokù rẹ̀ li o si fi ṣe ọlọrun, ani ere gbigbẹ́ rẹ̀, o foribalẹ fun u, o sìn i, o gbadura si i, o si wipe, Gbà mi; nitori iwọ li ọlọrun mi.

Ka pipe ipin Isa 44

Wo Isa 44:17 ni o tọ