Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 44:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni yio jẹ ohun idana fun enia: nitori yio mu ninu wọn, yio si fi yá iná; lõtọ, o dá iná, o si din akara, lõtọ, o ṣe ọlọrun fun ra rẹ̀, o si nsìn i; o gbẹ ẹ li ere, o si nforibalẹ fun u.

Ka pipe ipin Isa 44

Wo Isa 44:15 ni o tọ