Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 43:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati iwọ ba nlà omi kọja, emi o pẹlu rẹ; ati lãrin odò, nwọn ki yio bò ọ mọlẹ: nigbati iwọ ba nrìn ninu iná, ki yio jo ọ, bẹ̃ni ọwọ́-iná ki yio ràn ọ.

Ka pipe ipin Isa 43

Wo Isa 43:2 ni o tọ