Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 42:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn enia ti a jà lole ti a si ko li ẹrù ni eyi: gbogbo wọn li a dẹkùn mu ninu ihò, a fi wọn pamọ ninu tubu: a fi wọn fun ikogun, ẹnikan ko si gbà wọn; a fi wọn fun ikogun, ẹnikan ko si wipe, Mu u pada.

Ka pipe ipin Isa 42

Wo Isa 42:22 ni o tọ