Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 42:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lailai ni mo ti dakẹ́: mo ti gbe jẹ, mo ti pa ara mi mọra; nisisiyi emi o ké bi obinrin ti nrọbi; emi o parun, emi o si gbé mì lẹ̃kanna.

Ka pipe ipin Isa 42

Wo Isa 42:14 ni o tọ