Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 42:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ kọ orin titun si Oluwa, iyìn rẹ̀ lati opin aiye, ẹnyin ti nsọkalẹ lọ si okun, ati ohun gbogbo ti mbẹ ninu rẹ̀: erekùṣu, ati awọn ti ngbé inu wọn.

Ka pipe ipin Isa 42

Wo Isa 42:10 ni o tọ