Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 41:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tani o ti fi hàn lati ipilẹ̀ṣẹ, ki awa ki o le mọ̀? ati nigba iṣãju, ki a le wi pe, Olododo ni on? nitõtọ, kò si ẹnikan ti o fi hàn, nitõtọ, kò si ẹnikan ti o sọ ọ, nitõtọ, kò si ẹnikan ti o gbọ́ ọ̀rọ nyin.

Ka pipe ipin Isa 41

Wo Isa 41:26 ni o tọ