Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 41:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jẹ ki wọn mú wọn jade wá, ki wọn si fi ohun ti yio ṣe hàn ni: jẹ ki wọn fi ohun iṣãju hàn, bi nwọn ti jẹ, ki awa ki o lè rò wọn, ki a si mọ̀ igbẹ̀hin wọn; tabi ki nwọn sọ ohun wọnni ti mbọ̀ fun wa.

Ka pipe ipin Isa 41

Wo Isa 41:22 ni o tọ