Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 41:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati talakà ati alaini nwá omi, ti kò si si, ti ahọn wọn si gbẹ fun ongbẹ, emi Oluwa yio gbọ́ ti wọn, emi Ọlọrun Israeli ki yio kọ̀ wọn silẹ.

Ka pipe ipin Isa 41

Wo Isa 41:17 ni o tọ