Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 41:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ má bẹ̀ru; nitori mo wà pẹlu rẹ; má foyà; nitori emi ni Ọlọrun rẹ: emi o fun ọ ni okun; nitõtọ, emi o ràn ọ lọwọ; nitõtọ, emi o fi ọwọ́ ọ̀tun ododo mi gbe ọ sokè.

Ka pipe ipin Isa 41

Wo Isa 41:10 ni o tọ