Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 41:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

DAKẸ niwaju mi, Ẹnyin erekùṣu; si jẹ ki awọn enia tún agbara wọn ṣe: jẹ ki wọn sunmọ tosí; nigbana ni ki wọn sọ̀rọ: jẹ ki a jumọ sunmọ tosí fun idajọ.

Ka pipe ipin Isa 41

Wo Isa 41:1 ni o tọ