Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 40:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiyesi i, awọn orilẹ-ède dabi iró kan ninu omi ladugbo, a si kà wọn bi ekúru kiun ninu ìwọn: kiyesi i, o nmu awọn erekùṣu bi ohun diẹ kiun.

Ka pipe ipin Isa 40

Wo Isa 40:15 ni o tọ