Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 39:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Inu Hesekiah si dùn si wọn, o si fi ile iṣura hàn wọn, fadaka, ati wura, ati nkan olõrun didùn, ati ikunra iyebiye, ati ile gbogbo ìhamọra rẹ̀, ati ohun gbogbo ti a ri ninu iṣura rẹ̀: kò si si nkankan ti Hesekiah kò fi hàn wọn ninu ile rẹ̀, tabi ni ijọba rẹ̀.

Ka pipe ipin Isa 39

Wo Isa 39:2 ni o tọ