Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 38:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

LI ọjọ wọnni Hesekiah ṣaisàn de oju ikú. Woli Isaiah ọmọ Amosi si wá sọdọ rẹ̀, o si wi fun u pe, Bayi ni Oluwa wi, Palẹ ile rẹ mọ́: nitori iwọ o kú, o ki yio si yè.

Ka pipe ipin Isa 38

Wo Isa 38:1 ni o tọ