Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 37:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Isaiah si wi fun wọn pe, Bayi ni ki ẹ wi fun oluwa nyin, pe, Bayi ni Oluwa wi, Máṣe bẹ̀ru ọ̀rọ ti iwọ ti gbọ́, nipa eyiti awọn iranṣẹ ọba Assiria ti fi sọ̀rọ buburu si mi.

Ka pipe ipin Isa 37

Wo Isa 37:6 ni o tọ