Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 37:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyi ni o si jẹ àmi fun ọ, Ẹ jẹ ilalẹ̀hu li ọdun yi; ati li ọdun keji eyiti o sọ jade ninu ọkanna: ati li ọdun kẹta ẹ fọnrugbìn, ki ẹ si kore, ki ẹ si gbìn ọgba àjara, ki ẹ si jẹ eso wọn.

Ka pipe ipin Isa 37

Wo Isa 37:30 ni o tọ