Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 37:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oriṣa awọn orilẹ-ède ha gbà awọn ti awọn baba mi ti parun bi? bi Gosani, ati Harani ati Resefu, ati awọn ọmọ Edeni ti nwọn ti wà ni Telassari?

Ka pipe ipin Isa 37

Wo Isa 37:12 ni o tọ