Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 37:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi ni ki ẹ wi fun Hesekiah ọba Juda, pe, Má jẹ ki Ọlọrun rẹ, ẹniti iwọ gbẹkẹle, ki o tàn ọ jẹ, wipe, A kì yio fi Jerusalemu le ọba Assiria lọwọ.

Ka pipe ipin Isa 37

Wo Isa 37:10 ni o tọ