Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 36:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Eliakimu, ọmọ Hilkia, ti iṣe olutọju ile, ati Ṣebna akọwe, ati Joa, ọmọ Asafu akọwe iranti, wá sọdọ Hesekiah ti awọn ti aṣọ wọn ni fifàya, nwọn si sọ ọ̀rọ Rabṣake fun u.

Ka pipe ipin Isa 36

Wo Isa 36:22 ni o tọ