Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 36:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ máṣe fetisi ti Hesekiah: nitori bayi li ọba Assiria wi pe, Ẹ fi ẹ̀bun bá mi rẹ́, ki ẹ si jade tọ̀ mi wá: ki olukuluku nyin ma jẹ ninu àjara rẹ̀, ati olukuluku nyin ninu igi ọ̀pọtọ́ rẹ̀, ki olukuluku nyin si ma mu omi ninu àmu on tikalarẹ̀;

Ka pipe ipin Isa 36

Wo Isa 36:16 ni o tọ