Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 36:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Eliakimu ati Ṣebna ati Joa wi fun Rabṣake pe, Mo bẹ̀ ọ, ba awọn ọmọ-ọdọ rẹ sọ̀rọ li ède Siria, nitori awa gbọ́: má si ṣe ba wa sọ̀rọ li ède Ju, li eti awọn enia ti o wà lori odi.

Ka pipe ipin Isa 36

Wo Isa 36:11 ni o tọ