Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 36:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si di igbati o ṣe li ọdun ikẹrinla Hesekiah ọba, Sennakeribu ọba Assiria wá dótì gbogbo ilu olodi Juda, o si kó wọn.

Ka pipe ipin Isa 36

Wo Isa 36:1 ni o tọ